Home Orisirisi O jigbijigbi! Omokunrin yii fe se igbeyawo pelu olomoge meji lojo kan naa
Orisirisi - October 21, 2018

O jigbijigbi! Omokunrin yii fe se igbeyawo pelu olomoge meji lojo kan naa

Arakunrin kan, Monday Obukeni, ti setan lati dabira bayii.
Lojo Satide to n bo, yoo se igbeyawo pelu awon omobinrin meji.
Awon obinrin oloriire naa ni Ufuoma Ozoro ati Oghale Andrew.
Ilu Isoko, ni Delta State. Ni igbeyawo naa yoo ti waye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àmọ̀tẹ́kùn yẹ kó di ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ láìpẹ́ – Akeredolu

Àmọ̀tẹ́kùn yẹ kó di ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ láìpẹ́ – Akeredolu Ọrẹ Òtítọ́jù Sé wọ́n ní a kìí wí sí…