O kasiara, won da omi si Olori Ooni tuntun lese, Oba Ogunwusi naa rerin muse
Ilana asa Yoruba lori igbeyawo tun ti jeyo lasiko eto igbeyawo Olori tuntun ti Ooni Ile-Ife Oba Adeyeye Ogunwusi, sese gbe si aafin.
Obinrin naa ni Naomi Oluwaseyi.
Bi won se n mu u wo aafin, won da omi si I lese gege bi won se maa n se fun gbogbo iyawo Yoruba nigba kan.
Itumo eyi ni pe owo ero, owo tutu, owo alaafia ati ilosiwaju ni Oluwaseyi n gbe wole.
Leyin eyi ni won fa Olori naa le Ooni lowo, ti baba naa si rerin-in muse, gege bi opolopo oko iyawo se maa n se nigba ti wowo won ba ba ohun ti won n wa.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…