Salawa Abeni fi enu re iku danu
Gbajugbaja akorin waka, Alhaja Salawa Abeni, naa ti n dan mewaa wo lori ero alatagba Instagram o.
Ninu fidio kekere kan to sese gbe sita, a ri ti o n fi orin doweke, to n fi orin le iku jinna si sakaani re.
O n korin pe ‘Iku salo lodo mi/ Mo gbonra jigi, iku salo./ Arun salo lodo mi/ Mo gbonra jigi/ Iku salo.’
O tun n korin pe, ‘Iro le fi pa o, eke le fi se, awa ko la n’ibanuje/ Iro le fi pa.’
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…