Home Orisirisi EFCC fi Fayose si atimole ose meji
Orisirisi - October 18, 2018

EFCC fi Fayose si atimole ose meji

Leyin ti Gomina Ipinle Ekiti tele, Ogbeni Ayo Fayose, yan fanda lo ba ajo to n gbogun ti iwa ikowoje, iyen EFCC, awon naa ti bere si lo agbara ti won ni labe ofin lori re.
Fayose wo aso faari to kede fun EFCC pe oun ti de ba won lalejo, ti Gomina Ipinle Rivers, Alagba Nyeson Wike, ati Femi Fanikayode si tele lo sibe.
Sugbon awon mejeeji ti pada sile bayii latari bi EFCC se gba iyonda nile ejo pe ki awon le mu u sodo fun itopinpin fun ose meji.
Ajo naa ti gbe awon footo ile kan sita, ti won so pe owo ilu lo fir a won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…