Home Orisirisi Yegede! Kunle Afolayan ba Dakore dawoo idunnu ogoji odun
Orisirisi - October 14, 2018

Yegede! Kunle Afolayan ba Dakore dawoo idunnu ogoji odun

Asiko niyi ki awon ololufe osere Nollywood, Dakore Akande, maa ba a yo, tori o ti di eni ogoji odun.
Eyi tumo si pe awon osere bii Funke Akindele, Mercy Aigbe ati Omotola kii se egbe re, tori awon naa ti se ‘Happy Birthday’ ogoji odun.
Okan lara awon to n ba osere pataki naa yo ni gbajugbaja onifiimu, Kunle Afolayan.
O kii ku oriire, o si se adura fun pe atodun odun nii sawo atodunmodun.
Leyin pe Daokore si n se daadaa lode fiimu, Olorun fi igbeyawo ke e, tori aarin oun ati bale re si n dun moran-inmoran-in, ti Olorun si fi omo daadaa jinki re..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…