Home Orisirisi Ijoba mi ko ni fi aaye sile fun ‘stomach infrastructure’ – Fayemi
Orisirisi - October 14, 2018

Ijoba mi ko ni fi aaye sile fun ‘stomach infrastructure’ – Fayemi

Gomina to sese fe bere ise ni Ipinle Ekiti, Dokita Kayode Fayemi, ti so pe oun ko ni fi aaye sile fun iru eto isejoba ti Gomina to n lo, Ogbeni Ayodele Fayose, so di asa, iyen stomach infrastructure, nibi ti o ti maa n pin awon ohun tie nu n je fun awon eniyan, ti oun naa si maa n je amala, agbado, ati bee bee lo kaakiri adugbo.
Fayemi ni iru asa bee je eyi to ko abuku ba igbesi aye awon eniyan.
O ni ijoba ohun yoo sise lori opo nnkan to maa mu aye deran fun ara ilu, sugbon kii se bii ko so fun di alatenuje tabi ohun to jo ohun ti awon Hausa n pe ni Alimajeeri.
Gomina naa fi kun un pe opo nnkan to dara , eyi ti ohun se nigba ti oun je gomina lakoko, naa ni oun yoo tun se ni saa tuntun yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…