Home Orisirisi Alao Akala, Ladoja ati Gbenga Daniel wa lara awon ti Buhari ni ko gbodo lo si oke okun
Orisirisi - October 14, 2018

Alao Akala, Ladoja ati Gbenga Daniel wa lara awon ti Buhari ni ko gbodo lo si oke okun

gbenga_danieldownload
Awon gomina kan tele, Otunba Alao Akala, Senito Rasidi Ladoja (Oyo) ati Otunba Gbenga Daniel (Ogun) , wa lara awon ti Aare Muhammadu Buhari ti fi ofin depe won ko gbodo jade ni Naijiria bayii.
Aare lo agbara nla kan to sese gba labe ofin lori atigbogun ti iwa ibaje.
Awon eniyan ti won fura sip e won se owo ilu basubasu ni oro naa kan.
Awon naa niwonyi:

1. Sambo Dasuki
2. Saminu Turaki
3. Murtala Nyako
4. Adebayo Alao-Akala
5. Gabriel Suswam
6. Rasheed Ladoja
7. Orji Uzor Kalu
8. Danjuma Goje
9. Attahiru Bafarawa
10. Muazu Babangida Aliyu
11. Chimaroke Nnamani
12. Sule Lamido
13. Gbenga Daniel
14. Ibrahim Shehu Shema
15. Nenadi Usman
16. Bashir Yuguda
17. Jumoke Akinjide
18. Bala Mohammed
19. Abba Moro
20. Femi Fani-Kayode
21. Ahmadu Fintiri.
22. Air Marshal Alex Badeh
23. Vice Admiral A. D. Jibrin
24. Air Marshal Mohammed Dikko Umar
25. Sunday Ehindero
26. Air Marshal Adesola Amosu
27. High Chief Raymond Dokpesi
28. Waripamowei Dudafa
29. Justice Innocent Umezulike
30. Justice Rita Ofili-Ajumogobia;
31. Olisa Metuh
32. Chief Jide Omokore
33. Ricky Tarfa
34. Dele Belgore.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…