Mercy Aigbe soro buruku si awon to ni Gomina kan lo ra ile fun un
Lasiko yi ti Mercy Aigbe ko ba eni Kankan ja, yala okunrin tabi obinrin, awon eniyan kan tun ti tow obo o lenu o.
Koda, o ti ge won ni owo naa je.
Won ni gomina kan ni ile Yoruba, ni ipinle ti o gbajumo julo ni Naijiria, lo ra ile nla to sese ko si fun un.
Ninu idahun kan si oro naa, Mercy Aigbe ni usokuso ni won n so.
O ni ow oogun oju oun lo n fi kole. O wa fi kun un pea won to n so isokuso nipa oun ko tii ri nnkan kan. O ni mewaa n bo lona.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…