Home Orisirisi Iyawo Baba Sala lo koko se akiyesi pe o ti ku – Emmanuel
Orisirisi - October 9, 2018

Iyawo Baba Sala lo koko se akiyesi pe o ti ku – Emmanuel

images
Okan lara awon omo Baba Sala, Emmanuel Adejumo, ti se alaye bi baba re, Alagba Moses Adejumo, ti opo eniyan mo si Baba Sala, se ku.
O ni aisan kan ko se e dabi alara, ati pe oju oorun ni olojo ti de ba a.
Emmanuel, eni ti oun naa je osere tiaa, so pe ni irole ojo Sunday, Baba Sala je ounje ale ni nnkan bii aago mefa. O ni leyin eyi lo wo yara, to lo fi oorun reju.
Laipe re ni iyawo re kekere, ti won n pe ni Iya Rhoda, wole lo lati ki i. Sugbon gbogbo bi o se pe baba naa, ko da a lohun.
Eyi lo fa a ti obinrin naa sun mo bale re, to gbe e lowo soke, to si rip e o ti ba Olorun re lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…