Home LÁGBO ÀRÍYÁ Egbe oselu APC pidan fun Funke Adesiyan
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 9, 2018

Egbe oselu APC pidan fun Funke Adesiyan

O jo pe ehbe oslelu APC ti fi oselu han osere fiimu to fi Ibadan se ibujokoo, iyen Funke Adesiyan.
Bi ohun ti osere fiimu naa ba je otito, o dabi pe won pidan fun un ni.
Ni ojo bii meji seyin lo koko kede pe oun bori ninu ibo abele APC si ile igbimo asofin ipinle Oyo.
Inu re dun debi pe o dupe lowo Gomina Abiola Ajimobi ati awon eniyan.
Sugbon o ti gbe atejade miiran sita, nibi to ti so pe won ti gba asia egbe naa lowo oun, ti won sig be e fun elomiran.
O ni nipa bee, elomiran ni yoo soju efbe ninu ibo naa.
O ni bi o tile je pe oun gba ohun ti egbe wi, kii se ohun to dara to lati maa se atunti afowoyi leyin ti awon oludije ba fi owo goboi r foomu tan, ti awon eniyan dibo tan, ti awon oloselu wag be esi to yato si ti ibo jade.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…