Home Orisirisi Dele Odule ati Aderupoko sedaro Baba Sala
Orisirisi - October 9, 2018

Dele Odule ati Aderupoko sedaro Baba Sala

images
Agba osere meji kan, Dele Odule, ati Kayode Olaiya, ti a mo si Aderupoko, ti sedaro baba isale awon onikomedi, Alagba Moses Olaiya, iyen Baba Sala, eni to di oloogbe ni ale Sunday.
Gege bi Odule ati Aderupoko se so, won ni alawada ti ko legbe ni.
Won seranti bi o se bere ise alawada ati awon igbese to gbe ki nnkan le senu rere.
Odule ranti pe Baba Sala je akorin ri, o ni o sit un se majiiki naa ki o to wa pokan po lori komedi.
O ni eni kan to maa n fi gbogbo ara sise ni Baba Sala.
Aderupoko naa ranti bi awon se jo sise po.
O ni leyin ti awon ajifiimugbe, iyen pirates, ji fonran fiimu Baba Sala, eyi ti akole re n je Orun Mooru, awon pada si ere itage lati ri owo ti oloogbe naa ya ni banki lati se fiimu naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…