Home Orisirisi Paga! Iku pa Baba Sala
Orisirisi - October 8, 2018

Paga! Iku pa Baba Sala

Gbajugbaja alawada, Moses Olaiya, ti opo eniyan mo si Baba Sala, ti di oloogbe bayii.
Ni nnkan bii aago mewa ale ana Saunday ni o je Olorun nipe.
Gege bi atejade kan ti akowe iroyin Baba Sala, Isaac Haastrup, gbe jade, ile alawada naa to wa ni Ilesa ni o ku si.
Won fi kun un pe won ti gbe oku re si inu mosuari bayii, ni Wesley Hospital to wa ni Ilesa.
Lara awon fiimu nla nla ti Baba Sala se ni Orun Mooru ati Mosebolatan.
O si se opolopo ere ori itage naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…