Home Orisirisi Oludije Aare fun PDP: Atiku tabi Tambuwal?
Orisirisi - October 5, 2018

Oludije Aare fun PDP: Atiku tabi Tambuwal?

Ojo Satide ni awon omo Naijiria yoo mo eni ti yoo koju Aare Muhammadu Buhari ninu ibo Aare odun to n bo.
Awon omo egbe ati olori PDP wa ni Abuja bayii, ti won yoo si di ibo abele fun Aare ni ola.
Lara awon ti won n dije ni Atiku Abubakar, Aminu Tambuwa, Bukola Saraki, Rabiu Kwakwanso ati Atthairu Bafarawa.
Wahala die sele ni oni ni Abuja nigba ti o jo pea won olopaa digbo lu iko Saraki, ti a gbo pe won yin ibon ataju si won.
Awon olori egbe naa si lo ba ajo eleto idibo INEC naa lalejo, ti won si so pe
Opo eniyan gba pe ti a bad a a sile ti a tun un sa, Atiku Abubakar ati Tambuwal lo gbewon ju.
Won ni Atiku lo agbara lati mi Buhari logbologbo ju. Sibesibe, won ni Tambuwal naa ni ami olori lara.
Koda, won ni awon olori PDP gbagbo ninu re, ti won si fi kun un pe o seese ki awon bii meri lara awon oludije naa tori re sun seyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…