Home Orisirisi Idije Aare: Saraki ni oun ko ni tori Atiku kuro ninu idije
Orisirisi - October 5, 2018

Idije Aare: Saraki ni oun ko ni tori Atiku kuro ninu idije

Aare ile Igbimo Asofin, Dokita Bukola Saraki, ti so pe iro ni oro kan to n tan kale pe oun ti jawo ninu kikopa ninu idibo abele Aare ni egbe PDP.
O ni aheso oro lasan ni.
Awon kan ni o ti finnu findo fi idije naa sile tori Alhaji Abubakar Atiku.
Ola ni PDP yoo dibo yan eni ti yoo soju won ninu idibo Aare odun to n bo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…