Home Orisirisi Ambode jewo omo Akin f’egbe oselu APC l’Ekoo
Orisirisi - September 30, 2018

Ambode jewo omo Akin f’egbe oselu APC l’Ekoo

Yoruba bo, won ni “oruko nii roni, nigba ti oriki n ro eniyan”. Eyi lo difa fun gomina ipinle Eko, Akinwunmi Ambode. O ni ki awon egbe APC ma fi owo ro oun seyin, oun ni lati se gomina leekeji ni ipinle Eko. Ambode fi oro Yoruba bonu pe “ibi ti won ni ki gbegbe ma gbe lo n gbe ati wi pe ibi ti won ni ki tete ma te lo n te”.O ni ti asiko lati soro ba to, awon ara ilu maa gbo winrin – winrin lenu oun. O ni gbogbo asiri awon to fe ba oun figagbaga ni oun maa tu tan patapata. O ni iwonba ti oun so nipa Sanwo-olu ati awon to ku re je asiri ti ko bo rara nitori pe gbogbo iwe eri re lo wa ni owo oun.

Ibi ipade oniroyin ti Ambode pe l’Eko lonii ogbon ojo, osu kesan-an odun yii ni oro ti n bo ti gbogbo eniyan si n ko ha! ha!.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…