Home Orisirisi Iyan ogun odun: APC ja Adebayo Shittu danu tori aini satifikeeti NYSC
Orisirisi - September 28, 2018

Iyan ogun odun: APC ja Adebayo Shittu danu tori aini satifikeeti NYSC

Aise eto isinu ilu ti Minisita fun Oro Ibanisoro, Alhaji Adebayo Shittu, ro pe oro ere ni ti wa di laasigbo nla fun un bayii o.
Idi ni pe egbe APC ti ja a kule, ti won ni awon ko nii fun un laye lati dije fun ipo gomina.
Nipa bee, won ti yo oruko re danu bi eni yo jiga.
O dabi pe orin Ayinla Omowura, nibi to ti ni, ‘E kuro ni titi/ Numba yin o jade’ ni won n ko fun Shittu.
Dipo ti okunrin naa kiba fi darapo mo awon akegbe re to se NYSC ni odun 1979, oselu lo gbari mo, to si wole si ile igbimo asofin.
O ti n leri leka tele pe nipa kikopa ninu oselu, oun n sinru ilu naa ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…