Owo te okunrin meta to n gbe oogun buruku kiri lasiko atundi ibo Osun
Owo awon olopaa tit e okunrin meta kan to n gbe oogun buruku kiri bi eto idibo se n lo lowo ni Osogbo.
A ko mo boya afeeri ni, aluwo tabi modarikan.
A ko sit ii mo eni ti won n sise fun.
Sugbon awon meteeta ti wa ni atimole olopaa bayii.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…