Ronke Oshodi-Oke ba Alao Malaika dawoo idunnu
Opo eniyan lo n ki akorin fuji, Sule Alao Malaika, ku oriire omo tuntun lanti-lanti ti Olorun sese fi jinki idile re bayii.
Lara won ni osere fiimu, Ronke Osodi Oke, eni to sadura pe ki Olorun woo mo naa.
Ori ero alatagba Instagram ni Malaika ti se ikede oore Olorun naa.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…