Home Orisirisi Ambode setan lati koju Sanwo-Olu
Orisirisi - September 26, 2018

Ambode setan lati koju Sanwo-Olu

fc31b731d99d132108b11ce9886bb41b_L
Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti setan lati kopa ninu ibo abele APC, eyi ti yoo waye ni ojo kokandinlogbon osu yii.
O ni niwon igba ti awon alase APC ti ni ibo ni awon fi maa yan oludije ibo gomina ni Ipinle Eko, ti oun si ti gba foomu ti oun naa, oun setan lati kopa ninu ibo ohun.
Itumo eyi ni pe Ambode yoo koju eni ti awon oloye egbe kan ni awon n tele, iyen Jide Sanwo-Olu.
Ambode ni oun dupe lowo Asiwaju Bola Tinubu ati awon alase egbe yoku ti won fun oun ni anfaani lati sise sin ilu, ati pe fifun oun laaye leekan sii yoo fun egbe ni anfaani lati tubo sise itesiwaju ni Eko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…