Home iroyin Adeleke ke pajare pe won fe pa oun
iroyin - September 26, 2018

Adeleke ke pajare pe won fe pa oun

Oludije gomina ni PDP, Ademola Adeleke, ti ke gbajare pe awon alatako fe da emi oun legbodo.
Ninu leta kan to ko si awon alase orile-ede America ati ajo European Union, o ni o ti to eemerin ti won ti fe gba emi oun.
Bakan naa, o ni won se madaru ibo Satide ni, tori oun mo pe oun wole.
Sugbon ninu atejade miiran, o ni oun ni idaniloju pe oun maa wole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…