Home Orisirisi Kin lo sele si agunbaniro to subu si oju ona ni Eko?
Orisirisi - September 21, 2018

Kin lo sele si agunbaniro to subu si oju ona ni Eko?

Olorun Oba lo yo agunbaniro kan ti oruko re n je Babatunde Sodiq lojo Alaaruba, nigba to deede subu lule ni iu Eko.
Popona Adaranijo ni Somolu ni Sodiq subu lule si, to na gbalaja sibe, ti ko si le soro tabi dide.
Sugbon ori eni tii gbe alawo rere ko ni lo ni ki awon eniyan eleyinju aanu tete ri I, ti won sig be lo si ile iwosan.
A gbo pe ara re ti n ya ni osibitu naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…