Home iroyin Aini satifikeeti NYSC: Adebayo Shittu ni oun ko sẹ sofin rara
iroyin - September 21, 2018

Aini satifikeeti NYSC: Adebayo Shittu ni oun ko sẹ sofin rara

download (1)
Minisita fun Oro Ibanisoro, Alhaji Adebayo Shittu, ti so fun awon oniroyin pe loooto ni oun ko kopa ninu ise isinru ilu ti a mo si National Yoth Service Corps.
O ni sugbon oun ko se sofin rara.
Dipo bee, o ni leyin ti oun jade ni University of Ife ni 1978, ti oun si lo ile eko giga ti awon amofin, iyen Nigerian Law School, ni 1979, oun dije ibo, ti oun si bere sii sin ilu latigba naa, leyin ti oun wole.
O ni nitori naa, un ko se si ofin Naijiria, tori bayii bi oun se je minisita, oun si n sise sin Naijiria naa ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…