Home Orisirisi Adebayo Shittu naa bọ sinu awuyewuye aise NYSC
Orisirisi - September 21, 2018

Adebayo Shittu naa bọ sinu awuyewuye aise NYSC

Minisita fun Oro Ibanisoro, Alhaji Adebayo Shittu, naa ti ba ara re ninu awuyewuye aise ise isinru ile National Youth Service Corps.
Aipe yii ni oro satifikeeti NYSC naa yo owo okan lara awon minisita Aare Mhammadu Buhari, Iyaafin Kemi Adeosun, ninu awo.
Iwe iroyin alatagba Premium Times to koko gbe iroyin Adeosun jade naa lo tun taari ti Shittu si ita.
Won ni bi o tile je pe o pari eko giga re ni Obafemi Awolowo University ile Ife ni 1978, nigba ti ifafiti naa n je University of Ife, ko lo se ise isinru ilu.
Ninu iroyin kan ti won sese gbe sita, won ni awon ti ba Shittu soro, to si so pe loooto ni oun ko se agunbaniro.
Gege bi won ti so, bi o se pari eko re ni won dibo fun un gege bi omo ile igbimo asofin ipinle Oyo. O ni oun gba pe bi oun se w anile igbimo naa, oun n sinru ilu ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…