Home Orisirisi Ipadabo Jimi Agbaje n seru ba Abuja
Orisirisi - September 20, 2018

Ipadabo Jimi Agbaje n seru ba Abuja

download
Ipinnu Ogbeni Jimi Agbaje lati dije fun ipo gomina n Ipinle Eko ti tubo n ko awon alase egbe APC ni Abuja lominu bayii.
Ijoba Muhammadu Buhari ni a gbo pe inu re ko dun si bi awon olori egbe naa ni Eko se fe lo elomiran dipo Gomina Akinwunmi Ambode.
A gbo pe won n beru pe ipinnu naa le se akoba fun iye ibo ti won n reti ni Eko fun Buhari ninu ibo odun to n bo.
Ni bayii ti Agbaje tun ti wa fe pada sinu idije naa, awon APC Abuja tubo n kominu siwaju.
A gbo pe idi niyi ti Alaga Egbe naa, Adams Oshiomhole, ati awon gomina egbe naa fi n se ipade kan pelu Ambode ni Ipinle Imo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…