Eyi ni oju okunrin ti Linda Ikeji bimo fun!
Ni igbeyin-gbeyin, arabinrin Linda Ikeji ti foju okunrin to bimo fun han.
Fun osu mesan-an gbako to fi loyun lo fi fi oro naa si abe ahon so.
Sugbon bayii, o ni oruko omo naa ni Jayce Jeremi, eyi to mu ki awon amoye so pe arakunrin kan ti oruko re n je Sholaye Jeremi lo wa nidii eto naa.
Omo Itsekiri ni Ipinle Delta ni Jeremi.
O
E gbe atupale yii si abala Geesi, lati wo abala ti oju foda, ati pe se agbekale naa wa ni sise n telee, ki o ma sotumo re nu.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…