Home Orisirisi Jimi Agbaje setan lati ba Ambode/Sanwo-Olu dije ibo gomina Eko
Orisirisi - September 19, 2018

Jimi Agbaje setan lati ba Ambode/Sanwo-Olu dije ibo gomina Eko

O jo pe ede aiyede to wa laarin egbe APC ni Eko t ji Alagba Jimi Agbaje dide o. O ti ra foomu lati dije gomina labe asia egbe PDP.
O so fun awon oniroyin lonii pe opo awon eniyan kan lo ta oun nidii pe, o si fi kun un pe ohun setan lati koju ibo abele PDP.
Awon olori gbe APC ti keyin si Gomina Akiwunmi Ambode, ti won si ni Alagba Jide Sanwo-Olu ni awon fe lo fun ibi naa.
Gbogbo awon to ti be Asiwaju Bola Tinubu pe ko jebure lori Ambode ni won ko ri oju rere re.
Koda, iyawo goina naa, Iyaafin Bolanle Ambode sese be Asiwaju ni.
Sugbon, pabo naa lo ja si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…