Home Orisirisi Araye fe mo baba omo Linda Ikeji, o bi omokunrin ni Atlanta
Orisirisi - September 18, 2018

Araye fe mo baba omo Linda Ikeji, o bi omokunrin ni Atlanta

Gbogbo eyin ololufe gbajugbaja oniroyin lori alatagba, Linda Ikeji, e ku ewu omo o.
Olorun ti sogo fun un ni Atlanta, lorile ede Amerika, nibi to bi omokunrin lanti-lanti si.
Opo ololufe re lo ti n ki I ku oriire, ti won si n gba a ni adura pe Olorun a womo, ati pe otun miiran a kun un.
Sugbon sa, Linda si n ko won lokan soke lori pe ta ni o bi omo naa.
Latigba to ti loyun ni opo eniyan ti fe mo ta ni baale re, sugbon titi di oni, ko tii so o.
Koda, awon kan n ro pe boya olori Marvins Records, Don Jazzy, lo gbin agbado si Linda Ikeji ninu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…