Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ EFCC ati ajo Customs ni awon ko ni je ki Fayose salo sile okeere
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - September 17, 2018

EFCC ati ajo Customs ni awon ko ni je ki Fayose salo sile okeere

Ajo to n gbogun tiwa ikowoje ati eyi to n so bode – EFCC ati Nigerian Customs – ti so pe awon ko ni je ki Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose, raye sa kuro ni Naijiria.
Won gbagbo pe awon esun nla-nla ti won ka a si I lese ati jagidijagan to se lasiko to n se ijoba le fa ki o fe salo.
Nipa bee, EFCC ti so fun awon oga asobode pe ki won ma sunlo o.
Sugbon sa, Fayose naa ti laali EFCC. O ni alainikan-an-se ni won. O ni oun ko nibi kan ti oun maa salo, tori eni ti ko je ‘gbi’ kii ku ‘gbi’.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…