Home Orisirisi Ibo gomina: Eru Dangote n ba awon Omoluabi Osun
Orisirisi - September 13, 2018

Ibo gomina: Eru Dangote n ba awon Omoluabi Osun

Ajosepo to wa laarin ibu owo to n je Deji Adeleke ati oba awon olowo Afirika, Alhaji Aliko Dangote, ti n ba awon omo egbe APC kan ni Ipinle Osun leru o.
Ti e ko ba gbagbe, Deji Adeleke to je baba akorin pataki, Davido, ni egbon eni to n dije ipo gomina ni PDP ni Osun ninu ibo gomina to n bo, Ademola Adeleke. Deji Adeleke wa je ore fun Deji Adeleke, gege bi olowo se maa n sore olowo ti otosi n sore otosi.
Eredi eru ti awon omo APC naa n ba ni pe won lero pe Dangote n gbow fun Ademola Adeleke.
Awon ajo kan ti won pe ara won ni Omoluabi United ni ko dara ki okunrin naa se bee. Won si so pe ko soro jade lori ipa wo lo n ko ninu idibo naa, tori adake ma fohun, a ko mo teni to n se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…