Sowore ni won da tear gas lu oun ni aafin Ooni Ife
Oludije fun ipo aare, Omoyele Sowore, so pe oju oun ati awon eniyan to tele oun ri mabo ni aafin Ooni ti Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, lonii.
O ni lasiko ti oba naa n gba oun lalejo, awon eniyan kan digbo lu awon, ti won si yin ibon ataju tear gas si awon.
Koda, Sowore, eni to tun je oludasile iwe iroyin alatagba Sahara Reporters, so pe meji lara awon omo ile iwe to wa leyin oun ni won daku.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…