Home Orisirisi O YAGBE TI: Baba Suwe ni iro ni won pa mo oun, oun ko gbe cocaine
Orisirisi - September 10, 2018

O YAGBE TI: Baba Suwe ni iro ni won pa mo oun, oun ko gbe cocaine

Ni bayii, Baba Suwe ti fe gbe fiimu kan jade pelu akole O YA’GBE TI.
Fiimu naa lo fi gbe iriri re jade nigba ti awon ajo to n gbogun ti oogun oloro – NDLEA – mu u, ti won gbe e si atimole, tori won ni o gbe oogun oloro cocaine si ikun.
Baba Suwe so oro yii lasiko to n se iforowanilenuwo pelu awon oniroyin.
O ni oun ko foju kan kokeeni ri latigba ti won ti bi oun, ayafi igba ti oun de odo awon NDLEA.
Bakan naa, o ni iro funfun balau nip e oogun ni oun lo lati je ki kokeeni naa poora ni ikun un.
Baba Suwe ni isele naa se akoba fun ise fiimu ti oun n se, tori o fa oun seyin pupo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…