Home Orisirisi Baba Latin fi emi imoore han si MC Oluomo
Orisirisi - September 8, 2018

Baba Latin fi emi imoore han si MC Oluomo

images (1)
Apanilerin onifiimu, Baba Latin, ti oruko re gan-an n je Bolaji Amusan, ti se sadankaata fun gbajugbaja olori onimoto, AlhajiMusiliu Akinsanya.
O yombo okunrin ti opo eniyan mo si MC Oluomo nigba to n se arojinle kan lori ero alatagba Instagram.
O ni Olowo to maa n fi owo se aanu alaini ni MC Oluomo. O ni o maa n ran opo eniyan lowo, ti o si ti se bee fun oun gan-an.
Baba Latin wa gba a ladura pe oke, oke ni ola MC Oluomo yoo maa lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…