Home Orisirisi Baba mi maa n fi olopaa le mi kiri nigba ti mo sese bere ise orin – Davido
Orisirisi - September 6, 2018

Baba mi maa n fi olopaa le mi kiri nigba ti mo sese bere ise orin – Davido

Akorin hip hop, David Adeleke, ti opo eniyan mo si Davido, ti se alaye bi baba re Alagba Deji Adeleke, se maa n fi ilodi si re han si bi oun se yan ise orin laayo nigba ti oun wa ni ile iwe ni ilu oyinbo.
Davido ni inu bi baba oun nigba ti oun saw a si Naijiria lati se ise orin.
O ni ibi gbogbo ti oun ba ti n sere lagbo ni baba oun maa n da olopaa si. O ni baba oun a fi olopaa mu oun ati awon to n se agbodegba oun, ti a mo si promoters.
O ni ohun to yanju surutu naa ni bi awon se jo gba pe bi oun tile maa se ise orin ni Naijiria, oun gbodo bere ile iwe yunifasiti.
Bayii lo se lo si Babcock University.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…