Home Orisirisi Opo eniyan ba Alabi Pasuma gboriyiin fun iya re
Orisirisi - September 5, 2018

Opo eniyan ba Alabi Pasuma gboriyiin fun iya re

Inu opo idunu ni osere fuji pataki, Wasiu Alabi Pasuma, wa bayii. Koda, a le pe e ni idunnu onibeji.
Idi ni pe oni ni ojo ibi iya re ati okan ninu awon omo re, Omidan Opeyemi Alabi.
Opo eniyan lo ti n ba a yo latari eyi.
Nigba to n soro lori iya re, o ni iya to maa n duro ti omo lojo isoro ni iya oun. O ni iya naa lo ye ki won ma ape ni ‘opelope ejika ti ko je ki ewu bo sonu’.
O wa se e ni adura pe ki Olorun tubo lora emi iya naa ninu idunu pelu alaafia.
Bakan naa, Pasuma ni Opeyemi naa je omo rere to n mu idunnu ba oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…