Lola Idije, Yinka Quadri, Oyin Elebuibon ki Toyin Abrahams ku oriire
Gbogbo eyin ololufe Toyin Abrahams, ti o n je Toyin Aimakhu tele, e ku oriire oni o. Oni ni ojo ibi re, eyi to n waye leyin bii ose kan ti osere Yoruba miiran, Opeyemi Ayeola, naa se ojo ibi odun le ni ogoji.
Opo awon akegbe Toyin ni won n ba a jo, ti won n ba a yo pe Olorun da emi re si.
Lara won ni Lola Idije, Yinka Quadri, Oyin Elebuibon ati oniroyin kan ti oun naa ti n se fiimu, Samuel Olatunji.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…