Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ini Edo ko wo oruka igbeyawo re mo
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 5, 2018

Ini Edo ko wo oruka igbeyawo re mo

O jo pe awon ololufe osere fiimu pataki, Ini Edo, ti won ti n reti pe yoo se igbeyawo miiran laipe yii ni lati ni suuru die si o.
Ni nnkan bii osu kan seyin ni awon ololufe re n da ofun tolo, ti won n yo nigba ti won ri oruka kan to jo ti igbeyawo lowo re. Won wa ro pe o setan lati se igbeyawo miiran ni, tori eyi to se ni odun die seyin daru.
Sugbon ninu foto kan ti osere fiimu naa fi sori ero alatagba Instagram ni ana, IROYIN OWURO woye pe oruka naa ko si ni owo re. Boya ko si moomo wo o ni o, a ko tii le so.
Sibesibe, aimoye eniyan lo n kan saara si Ini Edo latari foto naa, ti won so pe o dara lewa bi ododo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…