Home Orisirisi Mo jogun apo babalawo lowo baba mi – Suara
Orisirisi - September 3, 2018

Mo jogun apo babalawo lowo baba mi – Suara

Osere fiimu pataki, Yemi Adeyemi, ti opo eniyan mo si Suara, ti se alaye pe bi o tile je pe onigbagbo ni oun, oun mo nipa ise babalawo.
O ni onigbagbo Kerubu ni iya oun sugbon babalawo ni baba to bi oun lomo.
O ni iya oun lo so oun di onigbagbo, sugbon oun gba pe igbagbo ko ni eniyan ju asa ati ise nu.
O ni oun jogun apo babalawo lowo baba oun, to si je pe baba-baba oun lo gbe e fun baba to bi oun lomo.
Suara so eyi lasiko to nsoro lori igbesi aye re, ninu iforowanilenuwo kan.
Suara ni baba oun ko fe ki oun sise tiata tele, sugbon o yi okan pada nigba toi oun bere sii ni ilosiwaju ninu ise naa.
Suara ti di eni aadorin odun (70 years), o si so pe oun dupe low Olorun.
O ni mejo ni awon omo oun, ti onikaluku won si n se daadaa nibi ise ti won yan laayo. Koda, adajo ni okan ninu won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…