Home Orisirisi Bi asiko eniyan ba to fun igbega, ko si eni to le di lowo – Odunlade Adekola
Orisirisi - September 1, 2018

Bi asiko eniyan ba to fun igbega, ko si eni to le di lowo – Odunlade Adekola

Osere pataki, Odunlade Adekola, ti so pe bi asiko eni kan ba to lati goke agba, ko si eda alaaye to le di oluware lowo.
Odunlade so eyi ni ale Satide, nigba to tewo gba ami eye Osere to Gbayi Julo Ninu Ere Apanilerin-in – Best Actor in Comedy – nibi idije African Movies Viewers’ Awards, eyi to n waye lowolow ni ile Eko.
Opo awon ore ati ololufe Adekola ni won suuru bo o, ti won ba a yo.
Lara won ni Femi Adebayo.
Odunlade fi idunnu re han, to si kan saara si gbogbo awon to se iranwo fun un, ati awon oludasile idije ti a mo si AMVCA.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…