Home Orisirisi Mo maa n wẹ oku eniyan ni ilu oyinbo ki n le ri owo ile iwe san – Ajimobi
Orisirisi - August 30, 2018

Mo maa n wẹ oku eniyan ni ilu oyinbo ki n le ri owo ile iwe san – Ajimobi

Gomina Ipinle Oyo, Senito Abiola Ajimobi, ti so asiri nla kan nipa igbe aye re.
O ni nigba ti oun wa ni ilu oyinbo nibi ti oun ti kekoo, oun maa n sise wiwe fun oku ki oun le ri owo ile iwe san.
Ajimobi ni awon obi oun kii se olowo to maa n ya owo lu omo to ba wa ni oke okun.
O ni dipo bee, ogbon dola (30 dollars) pere ni gbogbo ow ti wn fi ranse si oun ni gbogbo odun ti oun fi wa ni ile ajeji.
Ajimobi ni awon to gba oun sise weku-weku maa n di oun laya. Won maa n so pe ki oun ma beru awon oku naa rara. O ni won so pe ki oun ri awn oku naa gege bi eja inu yinyin.
Ajimobi se akawe oro yii nigba to n baa won odo langba kan soro ni Ipinle Osun, lati mu ki won ma roju, ki won tepa mose, ki won si mo pe bi eniyan ko ba ti roju, ti ko rera, ojo iwaju re yoo dara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…