Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Jonathan kan saara si Saraki
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 30, 2018

Jonathan kan saara si Saraki

Aare ana, Dokita Goodluck Jonathan, ti kan saara si Aare ile Igbimo Asofin Agba, Dokita Bukola Saraki, lori bo se n dari ile asofin naa.
O ni bi ko ba se akikanju ati ogbon ori to n lo, ile igbimo asofin naa kiba ti daru.
Nigba ti Saraki se abewo si Jonathan ni Abuja, o ni o wu oun bi ile igbimo asofin agba ati kekere ti House of Representatives se jo n sise papo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…