Home iroyin Gbegede fe gbina ni October 6 ninu egbe oselu PDP
iroyin - August 28, 2018

Gbegede fe gbina ni October 6 ninu egbe oselu PDP

Ojo kefa osu kewaa odun yii ni egbe oselu PDP mu fun idije du ipo Aare egbe naa. Won ti maa seto gbogbo ipo to ku bii ipo bii asoju ile igbimo asofin kekere ati agba, won maa se ti gomina ki eegun nla to keyin igbale ni ojo kefa , osu kewaa. Ojo yii n ko gbogbo omo Naijiria lominu pe ta ni yoo wole ibo abele egbe naa? Ara awon oludije ni a ti ri Atiku Abubarka, Bukola Saraki, Alagba Tambuwa, Alhaji Kwakwaso, Jonah Jang ati bee bee lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…