Home LÁGBO ÀRÍYÁ Moyo Lawal n wa okunrin ti won jo maa ba ara won sere
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 27, 2018

Moyo Lawal n wa okunrin ti won jo maa ba ara won sere

Asiko niyi ki awon okunrin ti won ba nifee si osere fiimu to saaba maa n dabira lori ero alatagba, Moyo Lawal, sun mo o tori o jo pe ara n rin in.
O so pe o ti pe ti oun ti ba okunrin ni ajosepo, debi pe oun ko ranti bi ibasun se n n ri lara mo.
O so ninu atejade re kan lori afefe pe ohun ti eyi tumo si nip e oun ko ni le koyin si gbogbo awon okunrin to n ko enu ife si oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…