Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ras Kimono, o digba! Oni ni won yoo sin oku re
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 25, 2018

Ras Kimono, o digba! Oni ni won yoo sin oku re

Oni ni akorin reggae pataki, Ras Kimono, yoo wole sun.
Ilu re ni Ipinle Delta ni won yoo sin okunrin naa to ku ninu osu kefa odun yii si.
Pelu ilu ati ifon ni awon akegbe re se gbe oku re lati Eko lo si Delta.
Bakan naa, won se ere ikeyin fun un, nibi ti opo alariya pejo si ni Eko, ti awon eniyan bii Majek Fashek ti korin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…