Home iroyin Okunrin to sa oba ni ada pa kii se were – Awon olopaa Ekiti
iroyin - August 25, 2018

Okunrin to sa oba ni ada pa kii se were – Awon olopaa Ekiti

5b7b3cd1eb6ec
Oga awon olopaa ni Ipinle Ekiti, Alagba Bello Ahmed, ti so pe okunrin kan to sa Onise ti Odo Oro, Oba Gbadebo Ogunsakin, ladaa pa ni ojo bii merin seyin kii se were.
O ni ori re ko daru, ohun to wu u lo se.
Ninu alaye re, Bello so pe nigba ti Omoniyi se ise ibi naa tan, o sa danu, ti ona re si ti jin ki owo awon agbofinro to te e.
Oga olopaa naa wa n beere pe bi ori re ba daru ko to pa oba, ori re se w ape lati salo?
Omoniyi ni idi ti oun fi pa oba naa ni pe oun lo ye ki oun joba.
O ni idile oun ti so pe oun ni ipo naa kan ki oba ti oun pa to fi agidi gba a.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…