Home iroyin Alaafin ba Ayefele be Ajimobi
iroyin - August 24, 2018

Alaafin ba Ayefele be Ajimobi

Yoruba bo, won ni agba kii wa loja ki ori omo tuntun o wo.
Boya idi niyi ti awon agbaagba ti bere sii da si oro wahala ile Yinka Ayefele ti ijoba Abiola Ajimobi fi ow ba ni Ibadan.
Ni bayii, Alaafin ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, ti parowa fun gomina pe ki o jowo jare boju aanu wo akorin naa, ki o si se irawo to ba ye lori bi won se so pe o se si awon ofin kan lori bi o se ko o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…