Eeru fun eeru, opo onimoto sunkun nibi isinku Fele, oga NURTW
Won ti sin oku Alaga awon onimoto NURTW fun agbegbe South-West ati Ipinle Oyo, Alhaji Tafeek Oyerinde, ti inagije re n je Fele.
Ojo Isegun ni o je Olorun nipe, leyin aisan kan ti won ni o se e.
Opo awon onimoto ni won wa nibi isinku naa, ti awon kan lara won si bara je debi pe won n baa won ebi ati ore Fele sunkun woru.
Ile nla Fele naa ni won sin oku re si ni Ibadan.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…