Home iroyin Awon omo Naijiria yari fun Miyetti Allah to n seru ba Saraki
iroyin - August 22, 2018

Awon omo Naijiria yari fun Miyetti Allah to n seru ba Saraki

O jo pe oro oselu Naijiria ti fe gba ibomiran yo o, latari bi egbe awon darandaran maalu ti Miyetti Allah Cattle Breeders Association se dun-kooko mo Aare ile Igbimo Asofin, Dokita Bukola Saraki.
Awon egbe naa so lojo Isegun pe bi Saraki ko ba kowe fi ipo re sile, awon yoo wa ona lati le e jade.
Oro naa ya opo omo Naijiria lenu, tori won gbagbo pe ikoja aaye, oorun ori keeke ki ni Miyetti Allah n se.
Awon ti won fi ehonu won han lori ero alatagba Internet ni kii se ohun to dara ki egbe olokoowo kan maa seru ba eni to wa nipo nla bii Saraki.
Lara iru awon to fi ehonu han ni Babasola Kuti, Oluwaferanmi, Olanrewaju Akinsola ati Ebuka Aakara.
Awon kan ninu won kominu pe igba ti ko ba si Aare Muhammadu Buhari nile, awon Miyetti Allah maa n mo iwon ara won, sugbon ti Buhari ba ti de, won a bere sii maa se ohun to wu won.
Ninu iroyin miiran, a ri i pe Saraki ti n ja pada lati gboriyin lowo awon to n lo ero alattagba Instagram.
Ni ana ojo Isegun, o ri pipon oju opo eniyan nigba to n ba won soro lori Ileya. Opo won ni bi Naijiria ba maa dara gege bi o ti wi, oun ati awon oloselu toku gbodo sini sise bii amusua.
Sugbon ninu awon ise miiran to ran si awon omo Naijiria lonii, opo awon to da a lohun ni won kan saara si I, eyi to tumo sip e awon to n sise iroyin fun un ko sun lo.
Esin kii da ni ka ma tun un gun ni won se e.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…