Home Orisirisi Tinubu n tele Buhari tori o fe di aare ni 20 23 ni – Saraki
Orisirisi - August 21, 2018

Tinubu n tele Buhari tori o fe di aare ni 20 23 ni – Saraki

Aare ile Igbimo Asofin, Dokita Bukola Saraki, ti fi ilodisi re han lori ohun ti Asiwaju Bola Tinubu so nipa ohun to le e kuro ninu egbe APC.
Tinubu so pe airi aaye maa pin owo ijoba lo le awon ti won n sa kiri.
Sugbon ninu atejade kan ti Akowe Iroyin Agba fun Saraki, Alhaji Yusuf Olaniyonu, gbe jade, o ni iro funfun balau ni Tinubu n pa.
O ni idi ti Tinubu ko fi kuro leyin Buhari nip e o fe di Aaare Naijiria ni odun 2023.
O ni iwa irenije ati aikanisi ti ijoba Buhari n hu si awon asofin lo fa a ti oun fi yose kuro egbe won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…