T’Eledaa lase, omo Naijiria meji ti ku si Mecca
Niwon igba to je pe kadara lau, to si je pe ti Eledaa lase, meji ninu awon omo Naijiria to n sise Haaji lowo ni orile-ede Saudi ni won ti je Olorun nipe.
Awon alase ajo to n seto irinajo mimo naa, iyen National Hajj Commission, lo se ikede yii.
Bi o tile je pe won ko daruko awon to ku naa, won ni okan wa lati Ipinle Eko, ti eni keji si wa lati Kano.
Arun ito suga – diabetes – ni a gbo pe o se awon mejeeji.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…