Mercy Aigbe fi ‘DINING ROOM’ re se forifori
Osere fiimu n fe ki gbogbo eniyan mo pe inu ola nla ni oun wa bayii o.
Ti e ko ba gbagbe, laipe yii ni Mercy ra ile nla tuntun kan ni ilu Eko.
Ninu foto kan, o ti wa se afihan bi ori tabili ti oun ti maa n jeun ati ibi ti o n ko oti waini si han.
Gbinrin ni gbogbo re n dan bii goolu, to si je pe eni to ba ri i yoo maa fi ibe se adura ni – tabi ko bu sekun gbagada pe bawo ni Olorun se se ti oun bayii…
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…